Ìdáfọ̀mọ̀ Noun Ìdá-ìfọ̀-mọ̀ Àbùdá Kíkọ́ Ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ l'ó bí Ìdá-ìfọ̀-mọ̀, Ọ̀rọ̀-di-ohùn àti Ohùn-di-ọ̀rọ̀-kíkọ-sílẹ̀. Machine learning feature gave birth to Speech Recognition, Text-to-Speech and Speech-to-text.
Kíkọ́ Ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ Noun Kíkọ́ ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ l'ó mú kí ìṣèṣàtúnkọ-ẹ̀rọ àti àsọtẹ́lẹ̀ ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọ̀rọ̀ ó ṣe é ṣe. Kíkọ́ ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ jẹ́ ètò òye tí-kìí-ṣe-ti-ẹ̀dá (AI) tí ó ń fi àyè gba ẹ̀rọ láti kọ́ ẹ̀kọ́ kún ẹ̀kọ́ fún ara rẹ̀ látàrí ìrírí láì ṣe wí pé allows ènìyàn fi ìmọ̀ bọ́ ọ. Pẹ̀lú àbùdá Kíkọ́ Ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ àwọn iṣẹ́ àìrídìmú leè ṣá ọ̀rọ̀ ìwífún alálàyé jọ fún...
Ẹ̀rọ-ìdíwọ̀n ìgbóná àti ìtútù Noun Ẹ̀rọ tí ó máa ń fi ìdiwọ̀n ìgbóná àti òtútù Ẹ̀rọ tí ó máa ń ṣe ìwọ̀ntúnwọ̀nsì sí ìgbóná tàbí ìtutù, ó sì tún máa ń mú ẹ̀rọ ṣiṣẹ́ bí ìgbóná/ìtutù bá dé ìwọ̀n kan. A device that automatically regulates temperature, or that activates a device when the temperature reaches a certain point.
Ihò-ìtẹ̀bọ̀ Noun Ti okùn afagbárainásẹ́rọ ìbánisọ̀rọ̀ bọ ihò-ìtẹ̀bọ̀ (sọ́kẹ́ẹ̀tì) Insert the phone charger into the socket Ihò-ìtẹ̀bọ̀ gbiná The socket exploded
Afagbárainásẹ́rọ Noun (A+fi+agbára+iná+sí+ẹ̀rọ) Fi afagbárainásẹ́rọ mi gbéná sínú òkúta-agbanására ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká rẹ Use my charger to charge the battery of your mobile phone
Pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́ Noun Ìsàlẹ̀ ojú-ẹ̀rọ niPátákó-gbọọrọ-iṣẹ́náà máa ń wà tí ó ní Bẹ̀rẹ̀, àwọn ààmì Pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́,... The Taskbar is at the bottom of the desktop and contains the Start, Taskbar icons,...
Ìpa ẹ̀rọ Noun (Ìpa ẹ̀rọ) Lọ sí pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́, wo ọwọ́ òsì, te Bẹ̀rẹ̀ kí o ṣira tẹ ìpa ẹ̀rọ. Go to the task-bar, on the left hand side, click on Start and click shut down. Pa ẹ̀rọ Verb Adéwálé pa ẹ̀rọ nígbà tí ó parí. Adéwálé shut down when he finished Adéwálé pa ẹ̀rọ ayárabíàṣá nígbà tí ó parí. Adéwálé shut down the computer...