22 Mar Off Profile root Ibi-òǹṣàmúlò Noun Ibi òǹṣàmúlò ni aṣojú tí í ṣe ìdánimọ̀ ẹni lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá. Mú ibi-òǹṣàmúlò Twitter rẹ ṣiṣẹ́ padà. A profile refers to the explicit digital representation of a person's identity. Reactivate your Twitter profile. TECHNOLOGY