19
Jan
Off
Kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú Noun Kíkọ-èdè-iṣẹ́ àìrímú [Kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú] Adébáyọ̀ ń kọ́ nípa ìmọ̀ kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú  Adébáyọ̀ is learning about programming. Kọ èdè-iṣẹ́ àìrídìmú  Write a program.    
3
Jun
Off
Kòkòrò aṣàṣìṣe Noun Ní ọjọ́ 9 oṣù Ọ̀wẹwẹ̀, 1947 Grace rí àṣìṣe kan ní orí ẹ̀rọ Mark II tí àfòpiná kan tí ó kú sínú rẹ̀ fà. Ó yọ kòkòrò náà ó sì lẹ̀ ẹ́ mọ́ ìwé àkọsílẹ̀, báyìí ni a ṣe hu èdè ìperí kòkòrò aṣàṣìṣe orí ẹ̀rọ ayárabíàṣá. Láti ìgbà náà lọ ni "kòkòrò aṣàṣìṣe" di èdè ìperí fún ìṣàpèjúwe àṣìṣe tàbí àléébù...
22
Mar
Off
Iṣẹ́-àìrídìmú Noun Fi iṣẹ́-àìrídìmú fún àwòrán yíyà sí orí ẹ̀rọ. Install graphic design Software on the system.