21
Mar
Off
Òkúta-agbanására Noun (Òkúta agba + iná + sára) Òkúta-agbanására ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ mi ti wú. My phone's battery has swollen.
21
Mar
Off
Ihò-ìtẹ̀bọ̀ Noun Ti okùn afagbárainásẹ́rọ ìbánisọ̀rọ̀ bọ ihò-ìtẹ̀bọ̀ (sọ́kẹ́ẹ̀tì) Insert the phone charger into the socket Ihò-ìtẹ̀bọ̀ gbiná The socket exploded
21
Mar
Off
Afagbárainásẹ́rọ Noun (A+fi+agbára+iná+sí+ẹ̀rọ) Fi afagbárainásẹ́rọ mi gbéná sínú òkúta-agbanására ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká rẹ Use my charger to charge the battery of your mobile phone
21
Mar
Off
Pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́ Noun Ìsàlẹ̀ ojú-ẹ̀rọ niPátákó-gbọọrọ-iṣẹ́náà máa ń wà tí ó ní Bẹ̀rẹ̀, àwọn ààmì Pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́,... The Taskbar is at the bottom of the desktop and contains the Start, Taskbar icons,...
21
Mar
Off
Ìpa ẹ̀rọ Noun (Ìpa ẹ̀rọ) Lọ sí pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́, wo ọwọ́ òsì, te Bẹ̀rẹ̀ kí o ṣira tẹ ìpa ẹ̀rọ.  Go to the task-bar, on the left hand side, click on Start and click shut down.   Pa ẹ̀rọ Verb Adéwálé pa ẹ̀rọ nígbà tí ó parí. Adéwálé shut down when he finished Adéwálé pa ẹ̀rọ ayárabíàṣá nígbà tí ó parí. Adéwálé shut down the computer...
21
Mar
Off
Àwòrán-olóhùn Noun Fi àwòrán-olóhùn mọ́ ọ̀rọ̀ náà. Attach the video with the text
21
Mar
Off
Ìpín Noun Ṣíra tẹ àtẹ̀ìpàṣẹ ìpín Click on the share button Pín Noun  Pín àwòrán-olóhùn náà. Share the video.
21
Mar
Off
Ààtò Noun Tún ààtò ibi-ìkọ̀kọ̀ orí Facebook rẹ̀ tò.  Reset the privacy setting on your Facebook.
21
Mar
Off
Ìfipamọ́ Noun Iṣẹ́ tí mo ṣe ń ṣe ìfipamọ́ sí inú àpò-àkápọ̀ àwòrán. The work I did is saving inside the picture folder Fi-pamọ́ Verb Fipamọ́ sí inú àpò-àkápọ̀ àwòrán. Save it in the picture folder. Ṣíra tẹ àtẹ̀ìpàṣẹ fipamọ́. Click on save button.
21
Mar
Off
Àpò-àkápọ̀ Noun Inú àpò-àkápọ̀ àwòrán ni mo fipamọ́ sí. I saved it inside the picture folder.