17
Mar
Off
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélétantẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ẹ̀rọ a + yára + bí + àṣá    À + gbé + lé + itan + tẹ̀ Pa ojú ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélétantẹ̀ yẹn dé kí o wá. Close that laptop (computer) and come.
17
Mar
Off
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélẹ̀tẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Brian ni ó ṣe ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélẹ̀tẹ̀ tuntun tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rà. Brian made the new desktop computer that I just bought.  
21
Jan
Off
Pátákó-ìdìmú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Pátákó-ìdìmú   Pátákó kékeré tí ó ní iga ìdìmú lórí, tí ó ṣe é mú ìwé (tákàdá) dání tí ó sì ń ṣe àtìlẹ́yìn fún ìkọ̀wé A small board with a spring clip at the top, used for holding papers and providing support for writing.   Ìtumọ̀ Mìíràn Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Pátákó-ìdìmú Nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ̀ ayárabíàṣà, pátákó-ìdìmú ni ìbi ìpamọ̀ ìgbà díẹ̀ tí...
27
Mar
Off
Ipò Noun Èyí ni atọ́ka sí ipò tí ẹ̀rọ tàbí ònṣàmúlò wà, fún àpẹẹrẹ; ipò ìjáde; ipò àìṣedéédé ẹ̀rọ... This is a pointer to the state (condition) of a device or user, for example; exit status, device malfunctioning status...