24
Sep
Off
Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ẹ̀rọ ìbára + ẹni + sọ̀rọ̀ oní + à + gbé + ká Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alòkúta-agbára-iná, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ ìléwọ́, tí a gé kúrú nígbà mìíràn sí ẹ̀rọ alágbèéká, ẹ̀rọ alòkúta-agbára-iná tàbí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ sàn-án, jẹ́ ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ tí ó ṣe é gbé kiri tí ó lè pè àti gba ìpè lórí ìsopọ̀ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ti oǹṣàmúlò náà sì...