14 Sep Off Animator root Asàwòrándààyè Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Asọ + àwòrán + di + ààyè A nílò asàwòrándààyè fún iṣẹ́ àkànṣe kan. We need an animator for a project. . TECHNOLOGY Uncategorized
14 Sep Off Animate root Sàwòrándààyè Ọ̀rọ̀-ìse (Verb) Sọ + àwòrán + di + ààyè Babájídé sọ àwòrán igi ọ̀pẹ dààyè.Babájídé animated a palm-tree. Wo animation. TECHNOLOGY
14 Sep Off Animation root Ìṣàwòrándààyè Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ìṣọ + àwòrán + di + ààyè Mo wo ìran ìsàwòrándààyè Ṣàngó kan lórí YouTube. I saw/watched a Ṣàngó animation on YouTube. TECHNOLOGY