Yobamoodua Cultural Heritage ṣí sílẹ̀ fún àjọṣe àti àjùmọ̀ṣe tí yóò ti àkànṣe iṣẹ́ àkópamọ́ ribiribi yìí síwájú. À ń gba aṣiṣẹ́-ọ̀fẹ́ fún ìgbéga iṣẹ́ ìràpadà yìí, a ṣe tán láti fi ọ̀rọ̀ tuntun kún àwọn tí ó ti wà nílẹ̀, ẹ fi tó wa létí, a ó sì gbé ìgbésẹ̀ lé e. Bákan náà ni à ń wá olùgbọ̀wọ́ fún ìtẹ̀síwájú iṣẹ́ ìlú náà.