Ìfèròkójọ jẹ́ àkójọ ìwífún, èròńgbà, tàbí iṣẹ́ láti ọwọ́ àwọn ènìyàn, tí ó jẹ́ wípé orí ẹ̀rọ ayélujára ni a ti kó o jọ. Iṣẹ́ ìfèròkójọ fi àyè gba àwọn ilé-iṣẹ́ láti dín àkókò àti owó kù bí wọ́n ṣe ń bù mu nínú omi ìmọ̀óṣe tàbí èrò ọkàn onírúurú àwọn ènìyàn jákèjádò ilé-ayé.
Crowdsourcing is the collection of information, opinions, or work from a group of people, usually sourced via the Internet. Crowdsourcing work allows companies to save time and money while tapping into people with different skills or thoughts from all over the world.