Read More 15 Sep Off Open Source Software root Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangba Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangbà Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangba ni àkọ́kọ́ irú àjùmòlò tí a tọ́ka sí t’ó so èso rere gẹ́gẹ́ bí i ìgbésẹ̀ àjùmọ̀ṣe tí ó ti sún síwájú rékọjá ìmọ̀-ẹ̀rọ lo. Open source software is cited as the first domain where networked open sharing produced a tangible benefit as a movement that went much further than technology. Using equipment or machines that operates (automatic) on its own. TECHNOLOGY Tags: Accessibility, In Yoruba, meaning of, Open, Open Access, Open Software, Open Source Software, Software, TECHNOLOGY, What is, Yoruba