14
Sep
Off

Device

Awo

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Awo

  • Ẹ̀rọ ìmọ̀ iṣẹ́ tàbí ohun tí a hùmọ̀ọ rẹ̀ fún ìdí kan pàtó; tí ó ń ṣe iṣẹ́ kan pàtó. Bí àpẹẹrẹ, ọgbọ́n, ìlànà-iṣẹ́, ète àti/tàbí ẹ̀rọ gẹ́gẹ́ bíi pátákó-ìtẹ̀wé, ẹ̀rọ gbohùngbohùn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

    A machine or an object that has been invented for a particular purpose; that does a special job. For example, initiative, procedure, and/or a machine like keyboard, microphone and etc.

Tags: , , , , , , ,