14
Sep
Off

Microscope

Awòhuntójúòlèrí

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Awò + ohun + tí + ojú + lásán + kò + lè + rí

  • Awòhuntójúòlèrí ni ohun èlò inú ilé àyẹ̀wò tí a fi ń ṣe ìwádìí àwọn ohun tí ó jógán gan-an tí ojú lásán kò leè rí.

A microscope is a laboratory instrument used to examine objects that are too small to be seen by the naked eye.

“My grandfather’s microscope” by Juan Eduardo Donoso is licensed under CC BY-NC-ND 2.0

Tags: , , , , , , ,