Read More 17 Mar Off Cinematograph root Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb) Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò Cinematography Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Yíyà àwòrán tí ń ṣípò Èyí ni ọnà àti ọ̀nà lílo ẹ̀rọ-ayàwòrán fi ṣe eré-oníṣe-aláwòrán. Ọlájídé kó ẹ̀kó ìmọ̀ yíyà àwòrán tí ń ṣípò. This is the art and methods of using cameras in making a movie. Ọlájídé is studying cinematography. Cinematographer Ògbóntarìgì nínú ọnà àti ọ̀nà yíyà àwòrán tí ń ṣípò. a specialist in the art and methods of film photography. TECHNOLOGY Tags: Cinema, Cinematograph, Cinematographer, Cinematography, Film, In Yoruba, meaning of, Movie, Translate, Translation, What is, Yoruba