Read More 16 Mar Off Demo root Ìfihàn ní gbangba Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ìfihàn ní gbangba Iléeṣẹ́ náà ṣe ìfihàn-ní-gbangba láti polówó ọjà rẹ̀ tuntun The company did a demonstration to promote her new product Ẹgbẹ́ akọrin tàkàsúfèé àṣẹ̀ṣẹ̀ dá ń ṣe ìfihàn ní gbangba fún ìgbáradì ìkáhùnsílẹ̀ àwo orin wọn The newly formed hip-hop group is doing a demo in preparation for the recording of its music album TECHNOLOGY Tags: Demo, Demonstration, In Yoruba, Language, meaning of, Tech, TECHNOLOGY, What is, Yoruba