Read More 19 Jan Off Vehicle root Ọkọ̀ Noun Ọkọ̀ Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ mẹ́wàá ni aṣojú wa ń gùn Our representative drives ten cars (vehicle). Ọkọ̀ òfuurufú Boeing 737 já Boeing 737 crashed. Ọkọ̀ ojú-omi ré ní Èkó Ship/boat/canoe sink in Lagos. Ọkọ̀ ojú-omi Ọkọ̀ akérò kan ní ìjàmbá ní orí afárá-kẹ́ta erékùṣù Èkó One commercial vehicle had an accident on the Lagos third-mainland bridge. Ọkọ̀ abẹ́-ibúomi Submarine. Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó fi òfin de ọkọ̀ alùpùpù ní ìpínlẹ̀ náà The Lagos state government banned motorcycle in the state. Ọkọ̀ ojú-irin/ọkọ̀-ilẹ̀ ni mo wọ̀ lọ sí Ìbàdàn It is a train that I boarded to Ìbàdàn. . TECHNOLOGY Tags: Aeroplane, Aircraft, Automobile, Boat, canoe, Car, kayak, Motorbike, Ship, Shuttle, submarine, Vehicle