3
Jun
Off

App

Iṣẹ́-orí-ẹ̀rọ

Noun

Iṣẹ́-orí-ẹ̀rọ 

  • Iṣẹ́-orí-ẹ̀rọ, tàbí ohun èlò orí ẹ̀rọ ni àwọn iṣẹ́ àìrídìmú tí ó wà lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá rẹ. Aṣàwáríkiri orí ayélujára, iṣẹ́ orí ẹ̀rọ fún ìkọ̀wé ránṣẹ́, ohun èlò ìtẹ-ọ̀rọ̀, ohun ìṣeré, àti àwọn ohun èlò gbogbo ní orí ẹ̀rọ ni iṣẹ́-orí-ẹ̀rọ.

An application, or application program, is a software program that runs on your computer. Web browsers, e-mail programs, word processors, games, and utilities are all applications.

Tags: , , , , , , , ,