Ìṣàn tààrà (DC) ni irúfẹ́ ìṣàn iná mànàmáná tí ó máa ń ṣàn tààrà sí ìhà kan ṣoṣo. DC ní igun méjì tí ó dúró fún + àti -, fún àpẹẹrẹ àwọn òkúta agbagbára-iná-sára gbogbo ni ó jẹ́ ìṣàn tààrà. Kí á má fi ikú wé oorun, agbára iná DC kì í ṣe ẹgbẹ́ra pẹ̀lú ti AC.
Direct current (DC) is an electric current which flows only in one direction. DC has polarity of + and -, for example all batteries are direct current. The power of DC can not be compared with that of AC.