Read More 15 Sep Off Automation root Ìdàṣiṣẹ́fúnrarẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ìdà + ṣiṣẹ́ + fún + ara + rẹ̀ Àdá + ṣiṣẹ́ + fún + ara + rẹ̀ Lílò irinṣẹ́ tàbí àwọn ẹ̀rọ tí ó ń dá ṣiṣẹ́ (fún ara rẹ̀) láì nílò ìkúnpá ẹ̀dá ọmọ ènìyàn. Using equipment or machines that operates (automatic) on its own. TECHNOLOGY Tags: Automate, Automatic, Automation, In Yoruba, Language, meaning of, Translate, Translation, What is, Yoruba