14
Sep
Off

Telescope

Awòhunjínjìn

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Awò + ohun + jínjìn

  • Awo tí a fi ń sọ nǹkan tí ó wà ní ọ̀nà jínjìn réré di nílá. Ó máa ń mú kí àyẹ̀wò sí àwọn ẹ̀dá ti ọ̀run àti àwọn nǹkan mìíràn nínú Èdùmàrè rọrùn.

A device used to magnify object from far distance. It makes analysis of the celestial bodies and universe easy.

“Telescope” by Ryan Wick is licensed under CC BY 2.0

Tags: , , , , , , ,