17
Mar
Off

Scanner

Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

  • Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán máa ń yí àwòrán padà sí ẹ̀dà àìrídìmú fún lílò lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá.
    .

Scanner converts images into digital versions for use on a computer.

 

 

 

Tags: , , , , , , ,