Pátákó kékeré tí ó ní iga ìdìmú lórí, tí ó ṣe é mú ìwé (tákàdá) dání tí ó sì ń ṣe àtìlẹ́yìn fún ìkọ̀wé
A small board with a spring clip at the top, used for holding papers and providing support for writing.
Ìtumọ̀ Mìíràn
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Pátákó-ìdìmú
Nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ̀ ayárabíàṣà, pátákó-ìdìmú ni ìbiìpamọ̀ìgbà díẹ̀ tí ohun tí a bá gé tàbí gbẹ̀da rẹ̀ láti ara iṣẹ́ kan máa ń wà fún ìgbélẹ̀ sínú iṣẹ́ mìíràn
In computing, clipboard is a temporary storage area where material cut or copied from a file is kept for pasting into another file.