3
Jun
Off

Backup

Ìkójọpamọ́

Noun

  • Ì + + jọ + pa + mọ́ 

Ìkójọpamọ́ ni ẹ̀dá iṣẹ́ tí a mú fi pamọ́ sí ìbòmíràn tí ó ṣe é gbà padà bí a bá pàdánù rẹ.

Backup is a copy of work taken and stored elsewhere so that it may be used to restore the original after a data loss event.

Verb

  • + jọ + pa + mọ́

Tags: , , , , ,