Read More 27 Mar Off Subscription root Ìsanwósí Noun Ìsan + owó + sí (to pay to have access to something) Mo ṣe ìsanwósí DSTV. I did a DSTV subscription. Ìfi + orúkọ + sílẹ̀ (to put down one’s name/register for a purpose; for access to something) Jẹ́ kí a lọ ṣe ìforúkọsílẹ̀ fún owó-ìlò-ayélujára Let us go for subscription for internet data. TECHNOLOGY Tags: In Yoruba, Language, Subscription