22
Mar
Off

Thermometer

Òṣùwọ̀n ìgbóná

Noun

  • Òṣùwọ̀n-ìgbóná ni ohun èlò tí a fi ń yẹ ìwọ̀n òtútù àti ìgbóná nǹkan wò láti mọ bí nǹkan náà ṣe tutù tàbí gbóná sí.

thermometer is an instrument for measuring or showing temperature (how hot or cold something is). 

Tags: , , , , , , ,