Ọ̀rọ̀ọ́-di-ohùn ni yó ka ohun t’ó wà lójú-ẹ̀rọ l’óhùn. Ọ̀rọ̀ọ́ di ohùn ni ọgbọ́n-àmúṣe àfọ̀ tí ó ń yí gbólóhùn ọ̀rọ̀ tí a kọ sílẹ̀ di ohùn. Nítorí àwọn tí kò ríran ni a fi pèsè ohùn àfọ̀ ti ẹ̀rọ tí yó “ka” ọ̀rọ̀ sẹ́tígbọ̀ọ́ òǹṣàmúlò.
It is Text-to-speech that reads what is on the screen using voice. Text to speech (TTS), is a form of speech synthesis that converts text into spoken voice output. Text to speech systems were first developed to aid the visually impaired by offering a computer-generated spoken voice that would “read” text to the user.