21
Mar
Off

Shut down

Ìpa ẹ̀rọ

Noun

(Ìpa ẹ̀rọ)

  • Lọ sí pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́, wo ọwọ́ òsì, te Bẹ̀rẹ̀ kí o ṣira tẹ ìpa ẹ̀rọ. 

Go to the task-bar, on the left hand side, click on Start and click shut down.

 

Pa ẹ̀rọ

Verb

  • Adéwálé pa ẹ̀rọ nígbà tí ó parí.

Adéwálé shut down when he finished

  • Adéwálé pa ẹ̀rọ ayárabíàṣá nígbà tí ó parí.

Adéwálé shut down the computer when he finished

 

Tags: , , , , , , , ,