Read More 21 Mar Off Runtime root Iyeìgbàìṣiṣẹ́ Noun Iye ìgbà, ìṣẹ́jú tàbí wákàtí tí iṣẹ́ àìrídìmú kan lò fi ṣiṣẹ́ ní orí ẹ̀rọ. The length of time a program takes to run. TECHNOLOGY Tags: Define, Definition, In Yoruba, Language, Runtime, Translate, Translation, Yoruba